Sabi Lyrics- Mohbad

Sabi Lyrics: Sabi is the most recent Mohbad song and music is composed by Unknown. Sabi Lyrics are penned by Mohbad. This song is published under the label of Mohbad.

Sabi Lyrics

Sabi Song Detail

Song: Sabi
Singer: Mohbad
Lyrics: Mohbad
Music: Unknown
Label: Mohbad

Sabi Lyrics

(No one is sleeker)

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi
K′owá w’orí mi, k′òtò saasi
Kíń má ṣe ya’wó l’ọ′wọ′ Lati
Mo m’orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí oh
Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)
K′owá w’orí mí, k′òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
Kíń má ṣe ya’wó l′ọ’wọ’ Lati
Mo m′orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán, ò b′omi sí garri
Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b’omi sí garri
Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?
Mo má j′àyé mí kọto fun fèrè oh
Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere oh
Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko’rè oko dé′lé oh
Wọn gùn’yàn mí kéré o
Mo fíìmù wọn fon fèrè oh
Nínú àyé, mí o kéré o
T′obà dé ìgbòrò, k’olo béèrè oh

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi
K’owá w′orí mi, k′òtò saasi
Kíń má ṣe ya’wó l′ọ’wọ′ Lati
Mo m’orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí oh
Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)
K′owá w’orí mí, k’òtò saasi (uhn-uhn, uhn)
Kíń má ṣe ya′wó l′ọ’wọ′ Lati
Mo m’orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b′omi sí garri
Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún
Huh, ọmọ ológo tó sabi
Ọmọ gbéra tán o, ò b’omi sí garri
Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?
Mo má j′àyé mí kọto fun fèrè oh
Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o
Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko’rè oko dé’lé oh
Uh, wọn gùn′yàn mí kéré oh
Mo fíìmù wọn fon fèrè oh
Nínú àyé, mí o kéré
T′obà dé ìgbòrò, k’olo béèrè oh

I will exalt You, Lord
For You have lifted me out
Has not let my foes to rejoice over me
(Timi Jay on the track)

Watch Sabi Mohbad Video Song

Sabi Song FAQ

Who wrote the lyrics of  “Sabi” song?

Mohbad has written the lyrics of “Sabi”.

Who is the singer of  “Sabi” song?

Mohbad has sung the song “Sabi”.

Who composed the music of  “Sabi” song?

Sabi song composed by Unknown.

You may also like...